Jeremiah 49:29

29 aÀgọ́ wọn àti agbo àgùntàn wọn ni wọn ó kó lọ;
àgọ́ wọn yóò di ìṣínípò padà
pẹ̀lú gbogbo ẹrù àti ìbákasẹ wọn.
Àwọn ènìyàn yóò ké sórí wọ́n pé;
‘Ẹ̀rù yí káàkiri!’
Copyright information for YorBMYO